Yoruba Community KANO - YCK

Yoruba Community KANO - YCK To project the aims and objectives of this organization in Kano and serve as a social interaction platform.

Open to all Yorubas and her lovers resident in Kano State.

12/05/2026

ÌWÚRE OJÓ-ÒNÍ
Bi Olúwa tin be ti Èmí Re si wa,gbogbo Adití Ogun ninu aye wa segbe ni Oruko Jesu...
🙏🙏🙏

10/05/2026
09/05/2026

E JÉKÍ Á GBÀDÚRÀ
Ni ti Ìwọ ati àwọn ẹbi rẹ, Ọlọrun kòní jẹ ki ẹ ṣe ẹru ẹgbẹ laṣẹ Èdumare. ÀMÍN!

08/05/2026

OLÚWA,gbogbo eni to fe tori mi da awon omo àti ebí mi lóró,e ba mi fi won sofo danu 🔥loruko Jesu
Amin👏👏

07/05/2026

Olúwa ni kin so fun o pe;
Lo máa múra,nítorípé o máa pe àpèje Ayo láìpé láìjìnà...
Yèyé re yen,yio di Ayeye lórúko Jésù....

06/05/2026

Tani eni ton lo AHÓN ÒDÌ tàbí ÒRÒ ÒDÌ,lati ba tiwa
jé níwájá OLÓORE wa
eni náà ko sèsín ayérayé loruko Jesu🙏

05/05/2026

Ìjókó ìkà ènìyàn nítorí Ìwo àti Ìdílé re láti da yin lóró, Olúwa finá tú won ká lórúko Jésù,Amin.
🙏🙏🙏

Address

27,Sanusi St. Sabon Gari
Sabon Gari

Telephone

+2348035876608

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Yoruba Community KANO - YCK posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Organization

Send a message to Yoruba Community KANO - YCK:

Share