Ewaede

Ewaede Asa ati ewa ede yoruba je oun pataki laye ode oni pelu idagba soke ero aye lu jara.

Ki asa ati ewa ede maa ba di oun igbagbe fun awon omo ka ro o jire, ni a se gbe iru eto bayi kale lati je ko je afani fun gbogbo awom omo bibi yoruba ati awon ololufe ede ati asa wa ja ke ja’do gbogbo agbanlaye. Igbagbo wa nipe nipa igbese ba won yi, asa ati ewa ede wa ki yi di oun igbagbe pelu ifowsowopo gbogbo wa. Iran yi, kiyio ku…be si ni igi kan ko le da ‘gbo se .Agba jo ‘wo la n fi so’ya.

Address

Hon. Ad3
Osogbo
234

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ewaede posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Organization

Send a message to Ewaede:

Share