AyoJesu GoldenMirror Foundation

AyoJesu GoldenMirror Foundation Strong passion of appreciating the sacrifices and prices paid by our parent. Loving , sharing, giving and celebrating. Parent are our GOLDENMIRROR.. Amen.

God bless us all.

22/02/2026

Mo moore Oluwa. Oluwasemiloore to po.
ModupeOluwa.

24/01/2026

Ojo ale nikan ko lo jaju...oni naa ni ipa to n ko lojo ale. Ejeki a se daadaa ka le ni ojo ale to dara.

27/11/2025

Oni ni ojo idupe ni Amerika.
A ku odun o.
Emi wa a se opo re laye.
Enu ope wa ko ni kan. Amin

09/10/2025

Mi o ni salaini ohun to Dara. Aago ire, ati ayo mi yo kun akunwosile. Amin.

06/10/2025

Iwalesin.
Tun iwa re se.
Ma hu iwa buruku ti yo ti ona ire mo elomiran. Ko da rara

06/10/2025

I gained 258 followers, created 3 posts and received 3 reactions in the past 90 days! Thank you all for your continued support. I could not have done it without you. 🙏🤗🎉

02/09/2025

Ayo ati alaafia ni a o fi la osu yi ja.
Olorun a fi oun to Dara te okan wa lorun. Amin .

01/07/2025

Modupe mosope Temi.
Ope oloore adaidatan.
Osu keje yi ma san wa si rere. Amin.

22/06/2025

Iwalewa.
Ejeki a ko awon omo wa ni Eko ile. O se pataki.
Ile la ti n ko eso ro 'de.

14/06/2025

Bẹẹni, Ojú tó rí ibi tí ò fọ́, ire ló ńdúró dè. Yóò pada bọ wa rire.

:
The eyes that saw evil and did not go blind, are waiting to see good.

:
[The best is yet to come; keep hope alive.]

Ire lójú Owo nri, ire la óò máa ri laṣẹ Èdumare.

A kú ojumọ.

25/05/2025

A ma sorire tomotoko.
A o ni fi aisan logba ni ola eledumare.
Mo ki eyin olorire oooo.

Address

Lagos

Telephone

+2348138503333

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AyoJesu GoldenMirror Foundation posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Organization

Send a message to AyoJesu GoldenMirror Foundation:

Share