Benefit Of Harbs.

Benefit Of Harbs. THIS PAGE IS FREE FOR UR HEALTH AND SPIRITUAL ISSUES. GOD HAS GIVING YOU FREELY WHAT YOU NEED TO SUCCEED IN LIFE,ITS LEFT TO YOU TO MAKE USE OF IT.

07/09/2022

ASIRI EBU OSHOLE OWO LATI DI OLOWO ATI OLOLA NI ODE AYE TO YARA GBERA NI KIAKIA TESTED AND CONFIRM ✔️

* Ako Alangba kan
* Abo alangba kan
* Ewe Ojukoro 16
* Eran elede
* Owu dudu ati owu funfun
* Ewe Ola
* Odindi Atare kan
* Otin Schnapps Cup kekere kan

SISE RE 👇

- A la aya ako alangba
- A o la aya Abo alangba
- A o wa ko gbogbo ifun inu ako alangba kuro
- A o tun ko gbogbo ifun inu abo alangba na kuro
- A o wa ko awon ifun mejeeji sinu ara won (ifun ako alangba sinu abo alangba, ifun abo alangba sinu ako alangba)
- A o wa ko ewe Ojukoro mesan sinu Abo
- A o ko ewe Ojukoro meje sinu ako
- Eran elede kekeke mesan sinu abo
- Eran elede kekeke meje sinu ako
- A o wa ran mejeeji pa lotooto pelu owu dudu ati funfun
- A o wa si aya awon mejeeji derawon
- A o fi #1,000 Tuntun we awon mejeeji papo
- A o gbe sinu ape ijonkan
- A o fi odindi atare nla kan si legbe
- A o wa ko ewe ola bo lori mole
- A o jo papo, a o lo kunna daadaa

LILO RE 👇

Ago kan oru (1 am) ni a o lo gbogbo ebu na pelu otin schnapps A o se adura owo si daadaa ki a to lo ebu na.

Walahi ti eyonu ba wa lara daada, a ma gba owo nla. O daju ni.

07/09/2022

*AWỌN ALA TI ONISE PELU IRIN AJO EDA ÈNÌYÀN*

Bíi obalala pe oun sá ìgbín loju ala
Ìtumọ:- Ifaseyin ni

Bíi obalala pe aja ùn gbo ee loju ala .
Ìtumọ:- gbàdúrà kii ota mase da ee láàmú.

Bíi obalala pe òun gbórò ìlú
Ìtumọ:- wapada gba ipe ABURÚ

Ti obalala pe oun jeun lori akita tabi osubu sinu erefo
Ìtumọ:- gbàdúrà kii omaba dii ẹni yẹpẹrẹ

Bíi obalala pe oun bá arare níí ilé family house e nii gbogbo igba níí ipò pe oun gbe ibẹ
Ìtumọ:- gbàdúrà ogun Ifaseyin tabi Amubo

Bíi obalala pe oun pọn omi ṣugbọn omi náà wà ùn danu
Ìtumọ:- gbàdúrà kii omase ríi asedanu lẹnu iṣẹ

Bíi obalala pe awon ìgbín po ninu yara re
Ìtumọ:- gbàdúrà kii òsì máṣe fii inú ilé ee ṣe ibùgbé

Bíi obalala pe oun gbe ajadi apẹrẹ daani níí gbogbo igba
Ìtumọ:- asedanu níí

Bíi ẹjẹ blood ba in jade loju arare níí gbogbo igba loju alá
Ìtumọ:- asedanu ni.

Bíi obalala pe egungun ùn fii ẹgba le ee loju ala.
Ìtumọ:- ota yìí dáa ee láàmú latara Egun idile

Bíi obalala pe oun yagbe larin àwùjọ
Ìtumọ:- àṣírí ee koni bo

Ejeki ama gbadura kii ato lemasun nii ale besini kii ayema ronú sun kii ìṣòro mase wọ inú ayé wa.

01/09/2022

Majemu tofe fi iku ojiji Sinu Irin ajo RE ati idile RE losu September yii.

Ri Amin se

Kiwon gbina Danu loruko Jesu

01/09/2022

Ise ti afi ya ile (house)tia sese gba (rent) si mimo
Lora imole merin candle
ki e bu Omi
ati perfume miss Paris,e da perfume na sinu Omi na,
ki e wa ka Psalm 24 sinu re ni eemeta
,ki e wa gba adura iyasimimo Si
Eo fin turari sinu ile na,eo wa ma won Omi na sinu awon yara ati Agbegbe na.ao tan imole na fun ojo meta.
AO bu iyo na si isale ki a to tan imole lelori fun ojo meta

31/08/2022

OGUN AWENU TODAJU

ISE AWENU JE IS TI O YE KI A MA SE NI GBOGBO IGBA, KI ABI KU MA SO OLOGUN DI EKE, ARA AWON ENIYAN PE ORISIRISI

EWE IYALODE FUNFUN KAN

OROGBO KAN

AKO KAHUN DIE

OSE DUDU DIE

AO LO GBOGBO RE PAPO, FUN IWE EKAN PERE
AO FI WE NI ALE, NI GBA TI A KO JADE MON RARA
NB : AO FI EPO PUPA PARA KI A TO WE OSE YI

ASIRI NBE LODO AWON AGBA LA GBA

28/08/2022

EYONU

Ao gbo ewe ewuro ti yio to we ao wa fo eyin ororo kan si ao bu iyo die si ao wa fi sinra ni ale. Eyonu
eleyi daaju daadaa.

27/08/2022

Good morning Family,Happy weekend.

God will answer every of our secret prayer beyond measures.God rely bless us with leaves/herbs now remains how much we know about it and there uses.

Do you know with herbs and the natural things around us you can fight Promise and fail? Check out our next post today.

Don't forget to invite friends and family to like and share our page.

Thank you for been part of us.

26/08/2022

Aku Ojumo o!
Iwosan Ito Sugar ti an pe ni Diabetes ni ao menuba leni, ema bawa kalo.

A o wa ewe efirin nla, ewe guova, ewe ejinrin, a o ko gbogbo re sinu Koko, a o bu omi(clean water) si ao se daada. Leyin Ose meji, ti a tiun lo agbo yi daada, ni owuro ati asale. Pelu Ogo olohun, won o ni ri sugar kankan lara wa biotiwu ki o kere mo ti won ba lo pada se ayewo ni ile iwosan. O daju.

26/08/2022

IFERAN GBOGBO AYE TODAJU.....

Ewe rerinkomi ao loja pelu erin ke_ke,ao gun dada ao su rogodo si ona meje obinrin mesan,ao mafi ikankan sinu okele ounje ao magbemi ire.

Address

Adeniji Street
Orile-Iganmu
23401

Telephone

+2349021396466

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Benefit Of Harbs. posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Organization

Send a message to Benefit Of Harbs.:

Share