Mothers Support Mother Tongue Initiative

Mothers Support Mother Tongue Initiative Egbe awa iya akomolede (Mother Support Mother Tongue Initiative) je egbe ti a da sile ni Pataki julo fun awa iya kaakiri agbaye lati ji giri si ojuse wa ge

Egbe awa iya akomolede (Mother Support Mother Tongue Initiative) je egbe ti a da sile ni Pataki julo fun awa iya kaakiri agbaye lati ji giri si ojuse wa gegebii oluko akoko fun awon omo wa nipa kiko won ni asa, ise ati ede ainibi won. A o ri wipe ede geesi ti gbile ju laarin awon omowa, opolopo ile ni won kii so ede abinibi won mo laarin ile, idi niyi ti a fi da ege yii kale
• Lati maa gba awon ma

ma wan ni iyanju lati maa so ede abinibi wa si awon omo wa
• Lati maa se koriya fun awon omo wa ti o nso ede yii pe won kii se ara oko
• Ati se eto kan gboogi ti a ti se alufabeeti ati onka Yoruba sinu fonran agbelewo fun gbogbo enia
• A o man kaakiri awon ile-iwe alakobere ati girama ni awon ojo ti won ba ya soto gegebii ojo asa (cultural days) ti a o gbaa si ori fonran lati se afihan re ni ori mohunma woran (telifisan)
• A o maa se eto idije ewi kika, itan aroso, orin kiko ni ede abinibi laarin awon omo ile-iwe alakobere ati girama kaakiri ile kootu oo jiire
• A ngbiyaanju takuntakun lati lo kaakiri awon ipinle kaaro oojiire lati se ifilole egbe yii nibiti awon lobaloba, ni joye nijoye iyawo awon gomina ni won yii o je iya isale egbee wa.

I am thrilled to celebrate 11 years on Facebook. Thank you for your unwavering support. I am grateful for your loyalty. ...
06/03/2025

I am thrilled to celebrate 11 years on Facebook. Thank you for your unwavering support. I am grateful for your loyalty. 🙏🤗🎉

Address

Lagos
Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Mothers Support Mother Tongue Initiative posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Organization

Send a message to Mothers Support Mother Tongue Initiative:

Share